Ádùrá àti Ìdáhùn Ádùrá (10)
Ọjọ́ Kẹwàá (10), Ọjọ́ Àìkú , Oṣù ́Kíní , Ọdún 2021 Ádùrá àti Ìdáhùn Ádùrá (10) Láti lè gbàdúrà gẹgẹ bí ìfẹ Ọlọrun, a gbọdọ jẹ kí ọrọ Ọlọrun jẹ kókó ádùrá náà. Ohun pàtàkì tó yẹ kí a mú lọ sínú iṣe gẹgẹ bí onigbagbọ ni wípé tí a bá ti fẹ gb’adua nipa ohun kan tàbí òmíràn, a gbọdọ máa […]
Read More